Tẹsalonika Kinni 5:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa dúpẹ́ ninu ohun gbogbo nítorí èyí ni ìfẹ́ Ọlọrun nípa Kristi Jesu fun yín.

Tẹsalonika Kinni 5

Tẹsalonika Kinni 5:15-27