Tẹsalonika Kinni 5:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará, à ń bẹ̀ yín pé kí ẹ máa bu ọlá fún àwọn tí ń ṣe làálàá láàrin yín, tí wọn ń darí yín nípa ti Oluwa, tí wọn ń gbà yín níyànjú.

Tẹsalonika Kinni 5

Tẹsalonika Kinni 5:6-18