Tẹsalonika Kinni 5:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ máa tu ara yín ninu, kí ẹ sì máa fún ara yín ní ìwúrí, bí ẹ ti ń ṣe.

Tẹsalonika Kinni 5

Tẹsalonika Kinni 5:4-12