Tẹsalonika Kinni 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò nílò pé a tún ń kọ̀wé si yín nípa ọ̀rọ̀ ìfẹ́ láàrin àwọn onigbagbọ, nítorí Ọlọrun ti kọ́ ẹ̀yin fúnra yín láti fẹ́ràn ọmọnikeji yín.

Tẹsalonika Kinni 4

Tẹsalonika Kinni 4:3-17