Tẹsalonika Kinni 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹni tí ó bá kọ ọ̀rọ̀ yìí, kì í ṣe ọ̀rọ̀ eniyan ni ó kọ̀ bíkòṣe Ọlọrun tí ó fi Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ̀ fun yín.

Tẹsalonika Kinni 4

Tẹsalonika Kinni 4:4-13