Tẹsalonika Kinni 4:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí ohùn àṣẹ bá dún, Olórí àwọn angẹli yóo fọhùn, fèrè Ọlọrun yóo dún, Oluwa fúnrarẹ̀ yóo sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run. Àwọn òkú ninu Jesu ni yóo kọ́kọ́ jinde.

Tẹsalonika Kinni 4

Tẹsalonika Kinni 4:6-18