Tẹsalonika Kinni 4:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí à ń sọ ọ̀rọ̀ yìí fun yín gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Oluwa, pé àwa tí a bá wà láàyè, tí a bá kù lẹ́yìn nígbà tí Oluwa bá farahàn, kò ní ṣiwaju àwọn tí wọ́n ti kú.

Tẹsalonika Kinni 4

Tẹsalonika Kinni 4:5-18