Tẹsalonika Kinni 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, èmi náà kò lè fi ara dà á mọ́, ni mo bá ranṣẹ láti wá wádìí nípa ìdúró yín, kí ó má baà jẹ́ pé olùdánwò ti dán yín wò, kí akitiyan wa má baà já sí òfo.

Tẹsalonika Kinni 3

Tẹsalonika Kinni 3:1-11