Tẹsalonika Kinni 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí a wà lọ́dọ̀ yín, a ti sọ fun yín tẹ́lẹ̀ pé a níláti jìyà. Bẹ́ẹ̀ ni ó sì rí, bí ẹ̀yin náà ti mọ̀.

Tẹsalonika Kinni 3

Tẹsalonika Kinni 3:2-6