Samuẹli Kinni 9:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di àfẹ̀mọ́júmọ́, Samuẹli pe Saulu lórí òrùlé, ó ní, “Dìde kí n sìn ọ́ sọ́nà.” Saulu dìde, òun ati Samuẹli bá jáde sí òpópónà.

Samuẹli Kinni 9

Samuẹli Kinni 9:20-27