Samuẹli Kinni 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé e lọ sí ilé Dagoni, oriṣa wọn; wọ́n sì gbé e kalẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ère oriṣa náà.

Samuẹli Kinni 5

Samuẹli Kinni 5:1-8