Samuẹli Kinni 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí àwọn ará Filistia gba àpótí Ọlọrun lọ́wọ́ àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n gbé e láti Ebeneseri lọ sí Aṣidodu.

Samuẹli Kinni 5

Samuẹli Kinni 5:1-5