Samuẹli Kinni 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Samuẹli bá sọ gbogbo rẹ̀ patapata, kò fi nǹkankan pamọ́ fún un. Eli dáhùn pé, “OLUWA ni, jẹ́ kí ó ṣe bí ó bá ti tọ́ lójú rẹ̀.”

Samuẹli Kinni 3

Samuẹli Kinni 3:10-21