Samuẹli Kinni 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Eli bi í pé, “Kí ni OLUWA wí fún ọ, má fi nǹkankan pamọ́ fún mi. OLUWA yóo ṣe sí ọ jù bí ó ti sọ fún ọ lọ, bí o bá fi nǹkankan pamọ́ fún mi ninu ohun tí ó sọ fún ọ.”

Samuẹli Kinni 3

Samuẹli Kinni 3:7-18