Samuẹli Kinni 28:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu kọ̀, kò fẹ́ jẹun. Ṣugbon àwọn iranṣẹ rẹ̀ ati obinrin náà bẹ̀ ẹ́ kí ó jẹun. Ó gbà, ó dìde nílẹ̀, ó sì jókòó lórí ibùsùn.

Samuẹli Kinni 28

Samuẹli Kinni 28:19-25