Samuẹli Kinni 28:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́, nisinsinyii, jọ̀wọ́ ṣe ohun tí mò ń tọrọ lọ́wọ́ rẹ fún mi. Jẹ́ kí n tọ́jú oúnjẹ fún ọ, kí o jẹ ẹ́, kí o lè lókun nígbà tí o bá ń lọ.”

Samuẹli Kinni 28

Samuẹli Kinni 28:19-25