Samuẹli Kinni 28:19 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo fa ìwọ ati Israẹli lé àwọn ará Filistia lọ́wọ́. Ní ọ̀la ni ìwọ ati àwọn ọmọ rẹ yóo kú; OLUWA yóo sì fa àwọn ọmọ ogun Israẹli lé àwọn ará Filistia lọ́wọ́.”

Samuẹli Kinni 28

Samuẹli Kinni 28:13-25