Samuẹli Kinni 28:18 BIBELI MIMỌ (BM)

O ṣàìgbọràn sí àṣẹ OLUWA, nítorí pé, o kò pa gbogbo àwọn ará Amaleki ati àwọn nǹkan ìní wọn run. Ìdí nìyí tí OLUWA fi ṣe àwọn nǹkan wọnyi sí ọ lónìí.

Samuẹli Kinni 28

Samuẹli Kinni 28:13-20