Samuẹli Kinni 27:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi pa gbogbo wọn, lọkunrin ati lobinrin, ó sì kó àwọn aguntan, mààlúù, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ati ràkúnmí wọn, ati aṣọ wọn, ó sì pada lọ bá Akiṣi.

Samuẹli Kinni 27

Samuẹli Kinni 27:2-12