Samuẹli Kinni 27:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà, Dafidi ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbógun ti àwọn ará Geṣuri, ati àwọn ará Girisi ati àwọn Amaleki, tí wọ́n ti ń gbé ibẹ̀ fún ìgbà pípẹ́, títí dé Ṣuri ati ilẹ̀ Ijipti.

Samuẹli Kinni 27

Samuẹli Kinni 27:2-12