Samuẹli Kinni 26:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá bèèrè lọ́wọ́ Ahimeleki, ará Hiti ati Abiṣai ọmọ Seruaya, arakunrin Joabu pé, “Ta ni yóo bá mi lọ sí ibùdó Saulu?”Abiṣai dáhùn pé, “N óo bá ọ lọ.”

Samuẹli Kinni 26

Samuẹli Kinni 26:1-9