Samuẹli Kinni 26:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi lọ lẹsẹkẹsẹ láti rí ibi tí Saulu ati Abineri, ọmọ Neri, olórí ogun Saulu, dùbúlẹ̀ sí. Saulu wà ninu àgọ́, àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sì pàgọ́ yí i ká.

Samuẹli Kinni 26

Samuẹli Kinni 26:1-10