Samuẹli Kinni 25:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ti wí pé, “Ṣé lásán ni mo dáàbò bo agbo ẹran Nabali ninu aṣálẹ̀, tí kò sí ohun ìní rẹ̀ kan tí ó sọnù. Ṣé bí ó ti yẹ kí ó fi ibi san ire fún mi nìyí.

Samuẹli Kinni 25

Samuẹli Kinni 25:15-24