Samuẹli Kinni 25:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó ti ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ lọ, tí ó dé abẹ́ òkè kan, ó rí i tí Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ ń bọ̀ níwájú.

Samuẹli Kinni 25

Samuẹli Kinni 25:12-27