Samuẹli Kinni 24:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi jáde, ó pè é, ó ní, “Olúwa mi ọba,” bí Saulu ti wo ẹ̀yìn ni Dafidi dojúbolẹ̀ láti bọ̀wọ̀ fún un.

Samuẹli Kinni 24

Samuẹli Kinni 24:1-10