Samuẹli Kinni 24:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa báyìí Dafidi dá àwọn eniyan rẹ̀ dúró, kò sì jẹ́ kí wọ́n pa Saulu.Saulu jáde ninu ihò náà, ó bá ọ̀nà rẹ̀ lọ.

Samuẹli Kinni 24

Samuẹli Kinni 24:1-8