Samuẹli Kinni 23:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi gbọ́ pé Saulu ń gbèrò ibi, ó pe Abiatari alufaa kí ó mú aṣọ efodu wá, láti ṣe ìwádìí lọ́wọ́ Ọlọrun.

Samuẹli Kinni 23

Samuẹli Kinni 23:1-15