Samuẹli Kinni 23:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá pe gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jọ láti gbógun ti Keila kí wọ́n sì ká Dafidi ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ mọ́ ìlú náà.

Samuẹli Kinni 23

Samuẹli Kinni 23:1-10