Samuẹli Kinni 23:28-29 BIBELI MIMỌ (BM)

28. Nítorí náà, Saulu pada lẹ́yìn Dafidi, ó sì lọ bá àwọn ará Filistia jà. Nítorí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ni wọ́n ṣe ń pe òkè náà ní Àpáta Àsálà.

29. Láti ibẹ̀, Dafidi lọ farapamọ́ sí Engedi.

Samuẹli Kinni 23