Samuẹli Kinni 23:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, Saulu pada lẹ́yìn Dafidi, ó sì lọ bá àwọn ará Filistia jà. Nítorí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ni wọ́n ṣe ń pe òkè náà ní Àpáta Àsálà.

Samuẹli Kinni 23

Samuẹli Kinni 23:24-29