Samuẹli Kinni 23:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni oníṣẹ́ kan wá sọ fún Saulu pé, “Pada wá kíákíá, nítorí pé àwọn ará Filistia ti gbógun ti ilẹ̀ wa.”

Samuẹli Kinni 23

Samuẹli Kinni 23:26-28