Samuẹli Kinni 22:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá pàṣẹ fún Doegi pé, “Ìwọ, lọ pa wọ́n.” Doegi ará Edomu sì pa alufaa marunlelọgọrin, tí ń wọ aṣọ efodu.

Samuẹli Kinni 22

Samuẹli Kinni 22:16-23