Samuẹli Kinni 20:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba jókòó níbi tí ó máa ń jókòó sí ní ẹ̀gbẹ́ ògiri, Jonatani jókòó ní iwájú rẹ̀. Abineri sì jókòó sẹ́gbẹ̀ẹ́ Saulu. Ṣugbọn ààyè Dafidi ṣófo.

Samuẹli Kinni 20

Samuẹli Kinni 20:22-28