Samuẹli Kinni 20:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi farapamọ́ ninu pápá, ní ọjọ́ àjọ̀dún oṣù tuntun, Saulu ọba jókòó láti jẹun.

Samuẹli Kinni 20

Samuẹli Kinni 20:17-31