Samuẹli Kinni 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bukun Hana: ọmọkunrin mẹta, ati ọmọbinrin meji ni ó tún bí lẹ́yìn Samuẹli. Samuẹli sì ń dàgbà níbi tí ó ti ń ṣe iṣẹ́ iranṣẹ sin OLUWA.

Samuẹli Kinni 2

Samuẹli Kinni 2:20-28