Samuẹli Kinni 2:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Eli a máa súre fún Elikana ati Hana aya rẹ̀ pé, “OLUWA yóo jẹ́ kí obinrin yìí bí ọmọ mìíràn fún ọ, dípò èyí tí ó yà sọ́tọ̀ fún OLUWA.”Lẹ́yìn náà, wọn yóo pada lọ sí ilé wọn.

Samuẹli Kinni 2

Samuẹli Kinni 2:15-24