Samuẹli Kinni 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Elikana pada sí ilé rẹ̀ ní Rama. Ṣugbọn Samuẹli dúró sí Ṣilo, ó ń ṣiṣẹ́ iranṣẹ sin OLUWA, lábẹ́ alufaa Eli.

Samuẹli Kinni 2

Samuẹli Kinni 2:8-14