Samuẹli Kinni 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọ̀tá OLUWA yóo parun;OLUWA yóo sán ààrá pa wọ́n láti ojú ọ̀run wá.OLUWA yóo ṣe ìdájọ́ gbogbo ayé,yóo fún ọba rẹ̀ lágbára,yóo sì fún ẹni tí ó yàn ní ìṣẹ́gun.”

Samuẹli Kinni 2

Samuẹli Kinni 2:9-17