Samuẹli Kinni 19:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì sọ fún Dafidi pé, “Baba mi fẹ́ pa ọ́, nítorí náà fi ara pamọ́ sí ibi kọ́lọ́fín kan lọ́la, kí o má ṣe wá sí gbangba.

Samuẹli Kinni 19

Samuẹli Kinni 19:1-4