Samuẹli Kinni 19:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu sọ fún ọmọ rẹ̀ Jonatani ati gbogbo àwọn iranṣẹ rẹ̀ pé kí wọ́n pa Dafidi. Ṣugbọn Jonatani fẹ́ràn Dafidi lọpọlọpọ.

Samuẹli Kinni 19

Samuẹli Kinni 19:1-7