Samuẹli Kinni 19:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn iranṣẹ náà dé, wọ́n bá ère ní orí ibùsùn pẹlu ìrọ̀rí onírun ewúrẹ́ ní ìgbèrí rẹ̀.

Samuẹli Kinni 19

Samuẹli Kinni 19:14-20