Samuẹli Kinni 19:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu tún rán àwọn iranṣẹ náà lọ wo Dafidi, ó sọ fún wọn pé, “Ẹ gbé e wá fún mi ti òun ti ibùsùn rẹ̀, kí n pa á.”

Samuẹli Kinni 19

Samuẹli Kinni 19:14-17