Samuẹli Kinni 18:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bọ́ aṣọ tí ó wọ̀ fún Dafidi, ó sì kó ihamọra rẹ̀ pẹlu idà ati ọfà ati àmùrè rẹ̀ fún un.

Samuẹli Kinni 18

Samuẹli Kinni 18:1-14