Samuẹli Kinni 18:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Jonatani bá bá Dafidi dá majẹmu, nítorí pé ó fẹ́ràn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀mí ara rẹ̀.

Samuẹli Kinni 18

Samuẹli Kinni 18:1-5