Samuẹli Kinni 17:55 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Saulu rí Dafidi tí ó ń lọ bá Goliati jà, ó bèèrè lọ́wọ́ Abineri, olórí ogun rẹ̀ pé, “Ọmọ ta ni ọmọkunrin yìí?”Abineri dá a lóhùn pé, “Kabiyesi, n kò mọ̀.”

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:50-58