Samuẹli Kinni 17:54 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi gbé orí ati ihamọra Goliati; ó gbé orí rẹ̀ lọ sí Jerusalẹmu, ṣugbọn ó kó ihamọra rẹ̀ sinu àgọ́ tirẹ̀.

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:46-58