Samuẹli Kinni 15:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun Ológo Israẹli kò jẹ́ parọ́, kò sì jẹ́ yí ọkàn rẹ̀ pada; nítorí pé kì í ṣe eniyan, tí ó lè yí ọkàn pada.”

Samuẹli Kinni 15

Samuẹli Kinni 15:25-35