Samuẹli Kinni 15:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Samuẹli bá wí fún un pé, “OLUWA ti fa ìjọba Israẹli ya mọ́ ọ lọ́wọ́ lónìí, ó sì ti fi fún aládùúgbò rẹ tí ó sàn jù ọ́ lọ.

Samuẹli Kinni 15

Samuẹli Kinni 15:20-35