Samuẹli Kinni 13:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọjọ́ meje ni ó fi dúró de Samuẹli, bí Samuẹli ti wí. Ṣugbọn Samuẹli kò wá sí Giligali. Àwọn eniyan bá bẹ̀rẹ̀ sí sá kúrò lẹ́yìn Saulu.

Samuẹli Kinni 13

Samuẹli Kinni 13:4-17