Samuẹli Kinni 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mìíràn ninu wọn ré odò Jọdani kọjá sí agbègbè Gadi ati Gileadi.Gbogbo àwọn tí wọ́n wà pẹlu Saulu sì wà ninu ìbẹ̀rù ńlá.

Samuẹli Kinni 13

Samuẹli Kinni 13:1-11